Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 516

Ko dara ki okunrin na ki o nikan ma gbe emi o se oluranlowo ti o dabi re fun u.

Meter: 6.6.4.6.6.6.4.

Scripture: Gen. 2:18

1

fKrist’ n’nu ogba Eden,

L’a gbe ti r’ase yi,

Ase Tire,

P’o ye f’eni meji

Ki won jo ma gbe po,

Ki won jo ma rin po

Ninu aye.

2

mpNje a k’ara wa jo,

Lati se ase yi:

T’ojo kini;

pJo, ma sai sokale,

K’O wa si arin wa,

Pelu ibukun Re;

Sokale wa.

3

mpK’awon mejeji yi,

T’a fe lati so po,

Le wa fun O

N’gba gbogbo ma ko won

N’ise won s’ara won,

Ki won si le repo

Tit’ aye won.