Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 525

O gbe owo Re le won O si sure fun won

Meter: 7.7.7.7.

Scripture: Mk. 10:16

1

mfJesu fe mi, mo mo be,

Bibeli l’o so fun mi;

Tire l’awon omode,

fWon ko l’agbara On ni.

2

pJesu femi En’t’O ku

Lati si orun sile;

mfYio we ese mi nu;

Je ki omo Re wole.

3

pJesu fe mi sibe si,

Bi emi tile s’aisan;

L’or’akete aisan mi

crY’o t’ite Re wa so mi.

4

mfJesu fe mi, y’o duro

Ti mi ni gbogb’ ona mi:

’Gba mba f’aye yi sile,

Y’O mu mi rele orun.