Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 526

Nwon o si je temi, li Oluwa awon omo ogun wi, li ojo na nigbati mo ba nsiro oso mi

Meter: 8.6.8.5. & Ref.

Scripture: Mal. 3:17

1

mf‘Gbat’ O ba t’ O ba de ’gba t’O ba de

Lati sir’ oso Re;

Gbogbo oso Re iyebiye,

Awon ti O fe.

CHORUS

fBi irawo owuro, won ns’ade Re loso

Ewa won oyo pupo, ewa f’ade Re.

2

mfYio ko jo, yio ko jo,

OSO ijoba Re;

Awon mimo, awon didan,

Awon ti O fe.

3

mfAwon ewe, awon ewe,

T’o fe Olugbala;

Ni oso Re iyebiye,

Awon ti O fe.