Hymn 528
Ti nyin ni gbogbo won, enyin ni ti Kristi.
Meter: 8.6.7.6.7.6.7.6.
Scripture: I Kor. 3:22 & 23
mfOre kan mbe fun omode
Loke orun lohun;
Ore ti ki yi pada,
T’ife Re ko le ku;
pKo dabi ore aye
Ti mbaje l’ododun;
fOre yi ye lati je
Oruko Re Owon.
mpIsimi kan mbe f’omode
Loke orun lohun;
F’awon t’o f’Olugbala
Ti nke “Aba Baba”,
di’Simi lowo iyonu,
Low’ ese ati ewu;
Nibi awon omode
pY’o simi titi lae.
mfIle kan mbe fun omode
Loke Orun lohun;
fNibiti Jesu njoba
Ile alafia!
diKo s’ile to jo l’aye
T’ale fi s’akawe;
fAra ro ’lukuluku;
Irora na d’opin.
crAde kan mbe fun omode
Loke orun lohun;
Eni t’o ba nwo Jesu,
Y’o ri ade na de;
Ade t’o fi fun gbogbo
Ti y’o fi fun gbogbo
mfAwon t’o wa oju Re
Ti won si fe nihin.
fOrin kan mbe fun omode
L’oke orun lohun;
Orin ti ko le su ni,
B’o ti wu k’a ko to!
mfOrin t’awon angeli
Ko le ri ko titi;
Krist’ ki s’Olugbala won
Oba l’o je fun won.
fEwu kan mbe fun omode
Loke orun lohun;
Harpu olohun didun!
Imo ’pe isegun;
Gbogbo ebun rere yi
L’a ni ninu Jesu;
pEwa eyin omode,
Ki won le je ti yin.