Hymn 53
Mo wa ninu emi li ojo Oluwa.
Meter: C.M
Scripture: Ifi. 1:10
1
fJe k’a yin Oluwa ‘simi
Pelu awon mimo,
Ti n f’ayo at’orin didun
Lo ‘simi ailopin
2
mfOluwa, b’a ti nranti Re
N’ibukun wa npo si;
Nipa orin iyin l’a nko
B’a ti y’ayo ‘segun
3
Lojo ayo yi l’Olorun,
Oro ayeraye,
F’ise nla han, t’o logo ju
Ti iseda aye
4
fO jinde, eni f’irora
DiRa gbogb’eda pada;
Ise nla ni dida aye,
PIdande ju yi lo.