Hymn 532
Kristi jiya lekan nitori ese wa, olotito fun alaisoto ki o le mu wa de odo Olorun.
Meter: L.M.
Scripture: I Pet. 3:18
1
mfJesu t’o wal’oke orun
pSokale d’eniyan, O ku;
Ninu Bibeli l’a le ri
Bi On iti ma se rere.
2
O nkiri, O si nse rere
O nla ’ju awon afoju;
Opo awon t’o si yaro
O sanu won, O si wo won.
3
Ju wonni lo, O wi fun won;
Ohun wonni t’Olorun fe;
O si se Eni t’o tutu;
Yoo si gbo t’awon ewe.
4
pSugbon iku t’O ku buru;
A fi ko s’ or’ agbelebu
Owo rere t’o se nkan yi,
pWon kan mo’gi agbelebu.
5
pBe l’O ku nitori yi na,
O d’eniyan, ko ba le ku;
Bibeli ni O t’orun wa,
K’Ole dari ese ji ni.
6
O mo b’eniyan ti buru,
O mo b’iya ese ti ri,
Ninu anu, Jesu wipe,
On ogba iya ese je.