Hymn 538
Awon omode si nke ninu Tempili wipe, Hosanna si omo Dafidi.
Meter: C.M.
Scripture: Mat. 21:15
1
fHosana! e korin s’oke
S’omo nla Dafidi
Pelu Kerub’ ati Seraf,
K’a yin Om’Olorun.
2
mpHosana! eyi na nikan
L’ahon wa le ma ko!
crIwo ki o kegan ewe
Ti nkorin iyin Re.
3
fHosana! Alufa, Oba,
Ebun Re ti poto!
Eje Re l’o je iye wa
Oro Re ni onje.
4
mfHosana! Baba awa mu
Ore wa wa fun O;
Ki ’se wura tab’ ojia
Bikose okan wa.
5
Hosana! Jesu lekan ri
O yin awon ewe;
crSanu fun wa, si f’eti si
Orin awa ewe.
6
Jesu b’O ba rawa pada,
T’a si wo ’joba Re;
A o fi fere wura ko
Hosana titi lae.