Hymn 540
O si gbe won lapa Re....... O si sure fun won.
Meter: C.M.
Scripture: Mk. 10:16
1
mfWo b’Olus’agutan Israel’
Ti fi ayo duro;
O npe awon Od’agutan,
O si kowon mora.
2
On si wipe, “ Je ki nwon wa”
“E mase k’egan won”
Lati sure fun iru won,
L’Oba angel’ se wa.
3
fPelu ope l’a gbe won wa,
A jewo won fun O,
Ayo: pe awa je Tire
K’omo wa je Tire.