Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 549

Iwo Olorun ninu ore Re li o ti npese fun awon talaka

Meter: C.M.

Scripture: OD. 68:10

1

mfOlorun, ite ogo Re,

Yio wa titi lae;

Obi wa, talaka ni won,

F’ibukun Re fun wa.

2

O wu O ni, lati se wa

pNi talaka; sugbon

Maa se alabojuto wa,

’Gbati a wal’aye.

3

A mo, b’atile je Tire,

T’ a j' oruko mo O,

A j'alejo; sugbon se wa

L’omo asayan Re.

4

Oluso agutan wa, wo

Agbo kekere Re;

F’Ogo at’opa Re to wa,

Omo agbo Tire.