Hymn 550
Lati enu awon omo-owo, ati omo omu, ni Iwo ti se ilana agbara.
Meter: 8.7.8.7.D.
Scripture: OD. 8:2
1
mfJehofa! Olorun ogo,
Je ki omode yin O;
pA wole n’irele fun O,
Ore Re ni orin wa,
Ogun Seraf’ dupo gberin
Ife Re l’oke orun;
Olorun ogo, gbo tiwa,
B’a ti nyin oruko Re.
2
Imanueli! Iwo t’a bi,
pT’a si fi ko or’ igi,
O pe omode kekere,
Lati wa si odo Re;
Oluwa, b’o ti pe, a de,
Je k’ari aanu Re gba!
K’awa, pel’ awon omo Re,
K’a sin O, k’a si fe O.
3
A ba le wa, k’a si fe O,
K’a si beru Rce l’aye;
Nikehin, k’a wa pelu Re,
fK’a ri O, k’a si yin O,
Jesu! Olorun itunu,
Olori ore! dide,
fFi igbala Re bukun wa,
JO tewo gba orin wa.