Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 552

Ojo nlo, ojiji ojo ale na jade.

Meter: 4.4.8.

Scripture: Jer. 6:4

1

pOj’ oni lo,

Jesu Baba,

Boju Re w’emi omo Re.

2

’WO Imole,

Se ’toju mi;

Tan imole Re yi mi ka.

3

Olugbala,

Nko ni beru

Nitori O wa lodo mi.

4

Nigba gbogbo

Ni oju Re

NSO mi, gbat’ enikan ko si.

5

Nigba gbogbo

Ni eti Re

Nsi si adura omode.

6

Nitorina

Laisi foya,

Mo sun, mo si simi le O,

7

Baba, Omo,

Emi Mimo

Ni iyin ye l’orun l’aye.