Hymn 559
A gbe awon Omo-Owo wa s’Odo re.
Meter: S.M.
Scripture: Mat. 19:13
1
Jesu pe omode,
O gbe won s’aya Re;
O f’owo Re gba won mora,
O si sure fun won.
2
pJesu gb’omode yi,
T’a gbe wa s’ile Re,
pTikala Re se ni Tire,
K’o dagba f’ogo Re.
3
pGb’ awon omode wa,
Ti won nwa waju Re,
ppSi pese f’awon ti ko ni,
fSure fun gbogbo wa.