Hymn 564
Ojo ibukun yo si ro
Meter: 8.7.8.7.6.7.
Scripture: Esek. 34:26
fOluwa, mo gbo pe, Iwo
Nro ojo ’bukun kiri;
Itunu fun okan are,
Ro ojo na s’ori mi.
An’ emi, an’emi
ppRo ojo na s’ori mi.
An’ emi, an’emi
Je k’anu Re ba le mi.
An’ emi, an’emi
Pe mi mo awon t’O npe.
An’ emi, an’ emi
Soro ase na simi.
An’emi, an’emi
Tu mi, k’O dariji mi.
An’ emi, an’emi
Gbe gbogbo re ga n’nu mi.
An’emi, an’ emi
pMa sai fi’bukun fun mi.
mfMa koja, Baba Olore,
Bi ese mi tile po,
’Wo le fi mi sile, sugbon
pJe k’anu Re ba le mi.
mfMa koja, mi, Olugbala,
Je k’emi le ro mo O,
crEmi nwa oju rere Re,
pPe mi mo awon t’O npe,
mfMa koja mi, Emi mimo,
’WO le laju afoju,
Eleri itoye Jesu,
pSoro ase na simi,
mpMo ti sun fonfon nin’ese,
Mo bi O ninu koja,
ffAye ti de okan mi, jo,
pTu mi, k’O dariji mi,
crIfe Olorun, ti ki ye,
Eje Krist’ iyebiye,
ffOre-Ofe alaini won
diGbe gbogbo re ga n’nu mi.
mpMa koja mi, dariji mi,
Fa mi mora, Oluwa,
cr’Gba O nfi’bukun felomi
Ma sai f’ibukun fun mi,