Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 566

E ma ko gbogbo aniyan nyin le e.

Meter: 10.8.10.8. & Ref.

Scripture: I Pet. 5:7

1

pSo gbogbo ’banuje re fun Jesu

Ati gbogbo aniyan re;

Dajudaju yio da O n’ide,

On yio si tu O ninu.

CHORUS

mpSO won fun Jesu,

SO won fun Jesu,

So won fun Jesu,

On y’o gbo;

Sa gbekele ki

O si gba A gbo;

On yio si tu O ninu.

2

mpSo won fun Jesu Olugbala re

SO won k’o si ri ’gbala Re;

Mase se Jesu, mase d’oju ti,

On yio si tu O ninu.

3

crSo won fun Jesu, On ni abo re,

LO si odo Re fun anu;

SO fun Jesu, gbagbo ’WO O si ri

Ore-ofe ati ’tunu.