Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 571

O ye ki enia ma gbadura nigbagbogbo laisimi ati lai sare

Meter: 10.10.

Scripture: Lk. 18:1

1

mfMa gbadura; Emi mbebe, n’nu re,

Fun gbogbo aini re igba-gbogbo.

2

mpMa gbadura; l’abe eru ese,

Adura nri eje Jesu ti nsan.

3

Ma gbadura; b’are tile mu O,

Adura ngbe wa s’eba ’te Baba.

4

crMa gbadura; n’nu wahala aye,

Adura l’o nfun okan n’isimi.

5

fMa gbadura; b’ayo ba yi o ka,

crAdura nlu harp o nkorin angel’.

6

pMa gbadura b’awon t’o feran ku,

crAdura mba won mu omi iye.

7

diGbogb’ ohun aye y’o b’aye koja,

mfAdura wa titi; ma gbadura.