Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 579

Nitori nibe ni Oluwa gbe pase ibukun.

Meter: L.M.

Scripture: OD. 133:3

1

fPase ’bukun Re t’oke wa

Olorun, s’ara Ijo yi;

mfFi ife ti Baba wo wa

p’Gbat’ a f’eru gb’oju soke.

2

mfPase ibukun Re, Jesu,

K’a le se omo eyin Re;

Soro ipa s’okan gbogbo,

pSo f’alailera, ’tele mi.

3

mfPase ’bukun l’akoko yi

Emi oto, kun ibi yi,

mfF’agbara iwosan Re kun,

At’ ore-ofe isoji.