Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 58

Awon ne emi o si mu wa si oke mimo Mi, emi o si mu inu won dun, ninu ile Adua mi.

Meter: L.M

Scripture: Isa. 56:7

1

fAyo l’ojo ‘simi fun mi,

At’agogo at’iwasu;

PGbat’a ba mi n’nu ‘banuje

MfAwon l’o nmu inu mi dun

2

Ayo si ni wakati na

Ti mo lo n’nu agbala Re;

Lati mo adun adura

Lati gba manna oro Re

3

fAyo ni idahun “Amin”

T’o gba gbogbo ile na kan,

Lekokan l’o ndun t’o nrole,

O nkoja lo sodo Baba

4

B’aye fe f’agbara de mi

Mo ise ijo mefa re;

mfOluwa, jo, tu ide na,

K’o so okan mi d’ominira