Hymn 581
Ki ore-ofe Oluwa wa Jesu Kristi ki o wa pelu nyin.
Meter: 8.7.8.7.8.7.
Scripture: I Tes. 5:28
1
mfFi ibukun Re tu wa ka,
Fi ayo kun okan wa;
K’olukuluku mo ’fe Re
fK’a l’ayo n’nu ore Re;
CHORUS
Tu wa lara tu wa l’ara
La aginju aye ja.
crKi oju Re, ki oju Re
Ma ba wa gbe titi lo.
fK’a si joba, k’a si joba
Pelu Kristi titi lae.
2
fOpe at’iyin l’a nfun O
Fun ihinrere ayo;
mfJe ki eso igbala Re,
Po l’okan at’iwa wa;
3
pNje n’igbat’aba sipe wa
Lati f’aye yi sile
crK’ Angeli gbe wa lo s’orun,
L’ayo ni k’a j’ipe na;