Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 582

Olorun ore-ofe gbogbo ti o ti pe n yin sinu ogo Re ti ko nipekun ninu Kristi Jesu.

Meter: 8.7.8.7.D.

Scripture: I Pet. 5:10

1

fWa, iwo isun ibukun,

Mu mi korin ore Re;

Odo anu ti nsan titi

Bere orin ’yin kikan;

Oluwa, ko mi l’orin na

T’ogun orun nko l’oke

Je ki nroyin isura na

Ti ife Olporun mi.

2

mfNihin l’a ran mi lowo de

Mo gbe Ebenezer ro

crMo nreti nipa anu Re

Ki ndede l’alafia;

pL’alejo ni Jesu wa mi,

’Gba mo §sako lo l’agbo

Lati yo mi ninu egbe

O feje Re s’ etutu.

3

crNit or’-ofe lojojumo

Ni ’gbese mi si npo si;

K’ ore-ofe yi ja ewon

Ti nse ’dena okan mi,

pKi nsako sa l’okan mi nfe

Ki nko Jesu ti mo fe

crOlugbala gba aya mi;

Mu ye f’agbara orun.