Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 583

Oluwa yio fi di alafia bu si i fun awon enia Re.

Meter: 10.10.10.10.

Scripture: OD. 29:11

1

fOlugbala, a tun fe f’ohun kan

Yin oruko Re k’a to tuka lo;

Ni ’pari ’sin, a dide lati yin;

pA o si kunle fun ibukun Re.

2

mpF’alafia fun wa, b’a ti nrele,

crJek’a pari ojoyi pelu Re;

mfPa aya wa mo, si so ete wa

T’a fi pe oruko Re n’ile yi.

3

mpF’alafia fun wa l’oru oni;

crSO okunkun re d’imole fun wa,

Ninu ewu, yo awa Omo Re,

mfOkun on ’mole j’okanna fun O.

4

mpL’alafia fun wa loj’ aye wa,

crRe wa l’ekun k’O si gbe wa ni ’ja,

mfLeyin gbogbo ijagun aye yi,

pPe wa, Baba, s’orun alafia.