Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 597

Ninu ohun gbogbo ki O le ni ipo ti o ga julo.

Meter: 10.11.11.11.

Scripture: kol. 1:18

1

fJe iriran okan mi, Oluwa

Si je ohun rere gbogbo fun mi, Krist’

mfLosan, loru je ero mi to dara,

Ki O si je ’mole mi nigbagbogbo.

2

fJe oye mi, Oro otito mi;

Wa pelu mi, lai at’emi pelu Re;

mfJe Baba fun mi, k’emi je omo Re;

Ma gbe ’nu mi, k’a si je okansoso.

3

fJe abo mi, ida fun ija na;

Je ihamora ati agbara mi

mfJe ile agbara, abo okan mi;

To mi s’on’ orun, Alagbara julo,

4

fNko lepa oro tabi ’yin eda,

Je ipin mi nisiyi ati laelae;

mfWa, ko si je ekini n’nu okan mi;

Oluwa orun, IWO n’isura mi.

5

fOba giga orun, ’mole orun,

JO fun mi layo Re lehin isegun,

mfOkan Mimo julo, joba ninu mi,

Je ’riran okan mi, Alase eda.