Hymn 602
Nitori ti awa gbekele Olorun alaye.
Meter: 11.10.11.10.
Scripture: I Tim. 4:10
1
mfL’odo Re sibe nigbat’ ojumo mo,
Ti awon eye ji ti kuku lo;
Re koja t’orun ni didan imole,
Idaloju pe, “O wa lodo mi.”
2
pNigbati are mu okan mi togbe,
O ko ’ju si O ninu adura;
Orun na, ti dun to labe iji Re,
Sugbon k’a ji k’a ri O dun julo.
3
mfBeni, yoo ri l’owuro ikeyin ni,
Ti okan ji, ti kuku aye lo;
Gbana ninu ewa t’o ta t’orun yo
Ero, “mo wa pelu re yoo soji.