Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 606

Oluwa si nlo niwaju won.

Meter: 6.4.6.4.6.6.6.4.

Scripture: Eks. 13:21

1

mpFun mi n’iwa pele,

Okan tutu;

Ifarabale bi T’Oluwa mi;

pIrele on suru

At’opo iyponu,

crNinu ohun gbogbo

Ki njo Jesu.

2

mpFun mi n’itelorun

N’ipo k’ipo;

Ko le re ’le ju yi

T’ a bi Jesu.

pFun mi n’itunu Re,

At’iranlowo Re.

crNinu ohun gbogbo

Ki njo Jesu.

3

mpFun mi ni itara

S’ipa Tire;

Aniyan at’ife

S’ohun t’orun;

pFun mi n’iwa mimo,

Ikorira ese

crNinu ohun gbogbo

Ki njo Jesu.

4

mpFun mi ni igbagbo;

At’ireti;

Fun mi l’ayo ’gbala

Ninu Jesu;

fF’emi iye fun mi,

Fun mi l’ade ogo,

ff’Gba ti mo ba jinde

Ki njo Jesu.