Hymn 613
Nitori O wi ninu ara repe, bi mo ba sa le fi owo kan aso Re, ara mi o da.
Meter: 10.6.10.6.
Scripture: Mat. 9:21
1
Iseti Re lo f’owo kan
Bo ti sunmo ’do Re;
mfLarin opo eniyan to pejo
O si r’iwosan gba.
CHORUS
fDide, f’owokan aso Re;
IWO yo r’iwosan,
Ase iwosan Re sibe
Yo mu o lara le.
2
pTeruteru l’obinrin na wole,
Olugbala ti de;
mfAse iwosan jade lara Re
O si mu larada.
3
crJesu yipada, O soro ’tunu:
fMa lo pelu ’gbagbo;
Alafia de sin’ obinrin na,
Ayo kun okan re.