Hymn 63
Won nkigbe li ohun rara, wipe, Yio ti pe to Oluwa?
Meter: S.M
Scripture: Ifi 6:10
1
fAbe a fe ri O,
Ojo ‘simi rere
Gbogbo ose a ma wipe
Iwo o ti pe to?
2
O ko wa pe Kristi
FJinde ninu oku;
Gbogbo ose a ma wipe,
Iwo o ti po to?
3
O so t’ajinde wa
Gege bi ti Jesu;
Gbogbo ose a a wipe;
Iwo o ti o pe to?
4
mfIwo so t’isimi,
T’ilu alafia;
T’ibukun eniyan mimo,
Iwo o ti pe to!