Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 639

E ma sanu awon elomiran, E ma gba awon Elomiran la.

Meter: C.M.

Scripture: Juda 1:22-23

1

mfA ni ’se to logo kan se,

Ise ribiribi;

Ki gbogbo aye dapo mo wa,

Lati se ise na.

2

mp’Banuje kun opo ile,

T’alafia ko si;

crJe k’a f’ayo kun ’le wonyi,

K’a f’Olugbala han.

3

pEru o ti po yi wa ka,

Won nyira n’nu egbe;

crJe k’a da ewon t’o de won

K'a pa ibi na re.

4

pOpo aya pelu iya,

Nsokun fun ’banuje;

crJe ki a tu won ni inu

Pe, ireti si mbe.

5

pOpolopo l’awon omo

Ti mbe ninu ese;

crJe k’a yo won ninu okun

Si inu imole.

6

fJe k’a wo ihamora wa

Olorun n’ipa wa,

On l’o nsamona ogun wa,

Si ’segun t’o daju.