Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 644

Ijo awon ti o gbagbo si wa li okan kan ati inu kan.

Meter: S.M.

Scripture: Ise A. 4:32

1

mfAwa wa yin ife Re

To so okan wa po,

T’a njumo n’idapo didun

Bi won ti nse loke.

2

Nib’ ite Baba wa,

fA nf’itara bebe;

A njumo so edun wa fun,

A si nr’itunu gba.

3

mpA mb’ara wa kedun

A mb’ara wa y’ayo;

Ohunkohun t’o wu ko de,

A njumo f’ife pin.

4

mpB’ipinya base de,

O mba wa ninu je;

mfIbi kan wa fun idapo

Ti ore nri ‘ra won.

5

mfEyi n’ireti wa,

Ti nso okan wa ji;

fPe ao pade lai pinya

l’ese Jesu l’oke.

6

fA o bo low’aniyan,

Ao o lowo ese,

Ife pipe y’o so wa po

Titi ayeraye.