Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 647

Kiyesii, o ti dara, o si ti dun to fun awon ara lati ma jumo gbe ni irepo.

Meter: 6.6.6.6.8.8.

Scripture: OD. 133:1

1

mfW o b’o ti dara to

Lati wa l’alafia;

Eso ododo yi

fTi ndun m’Oba wa to,

Nigbat’ara wa n’irepo,

Ayo isokan ti dun to.

2

Nibiti sokan kan,

Nibe l’ore-ofe

Ntan si ohun gbogbo,

O si nya si mimo;

O nwa s’okan ti nreti re,

O si nfun-ni lohun t’orun.

3

mfLojojumo l’a nri

Or’ofe titun gba;

fIri ‘bukun ti nse

sor’ oke Hermoni!

O nse sori Sion pelu;

A npin n’nu ebun ara wa.

4

crNisiyi, Oluwa

Nro ojo ibukun

Pelu itura Re,

Ti ninu okan soji;

Akoro at’arokuro,

Ife Olorun at’eniyan.

5

Ipejopo ara

Ti nwa alafia,

Li On se ileri

Lati fi ire fun;

mfY’o fi opo ’re-ofe Re.

F’awon t’o pejo l’oko Re.

6

fO nf’ ekun ore Re

Fun awon t’o pejo

Awon ara Sion,

Omo-’bile orun

O nfi isura Re fun won,

Ati iye ainipekun.