Hymn 648
E wa, e je ki a korin si Oluwa.
Meter: 7.7.7.7.
Scripture: OD. 95:1
1
mfE wa, e jek’a jumo
F’orin mimo yin Kristi;
K’a f ohun kan fi ogo
Fun Oluwa gbogbo wa.
2
fK’agb’okan at’ohun wa
Soke bi t’aye ’gbani;
K’a bere ayo orun;
K’a s’ajo ase-ife.
3
A ngbiyanju n’nu ife;
crJek’ ina ife soji,
Ti njo n’nu awon martyr
T’oku n’tori Olorun.
4
Awa le ni’fe bi won,
Ale pin n’nu ayo won,
A gba wa lowo.’ binu,
Nipa igbagbo kanna.
5
fA nkorin iyin Jesu,
Okanna l’ana, l’oni;
Okanna nigbagbogbo,
Olore-ofe julo.
6
A duro f’Oluwa wa,
Bi ’mole ni’le okun;
Ajewo Jesu t’o ku
Awa ni eleri Re.
7
fEleri pe, Krist’ ti ku,
A kan awa Re mo ’gi,
Krist’ ti da ide iku,
Emi iye Re l’a nmi;
8
fKrist’ti goke lo s’orun,
On ni ife wa nfa si;
O wa l’otun Olorun;
Nibe l’ao ba joba.