Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 650

Nitori ojo wa gbogbo nyi po lo ninu Ibinu Re. awa nlo ojo wa bi ala ti a nro.

Meter: 14.10.8.8.15.10.

Scripture: OD. 90:9

1

pAkoko wa gbogbo l’o nyara sure koja lo

Won kun fun igba aro on ’rora,

mfSugbon 'fe Olorun npo si,

B’ojo atipo wa ti ngun

Bi nko tile fo ohun, okan mi nso inira na;

Un o sunmo Olorun, un o sunmo O.

2

mpIseju kokan nsun mi mo igbati un o pinya

Pelu aye t’o se owon fun mi

Iri ile si nhan si mi,

’Ranti orun s’owon fun mi

Ju ti aye pelu gbogbo ogo ati oro re,

Un o sunmo Olorun, un o sunmo O.

3

mfEni ’rapada Oluwa, e korin igbagbo

E fi ara ti oro Olorun,

E duro n’nu ileri Re,

Bi abo, e sa s’abe Re

fFi igboya rin ona t’awon ajeriku ti rin

Un o sun mo Olorun, un o sun mo O.