Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 652

Lati isisiyi lo a fi ade ododo lele fun mi.

Meter: C.M.

Scripture: II Tim. 4:8

1

mfIro ayo t’ihin-rere;

Krist’ y’o han ninu mi!

Ani emi y’o r’oju Re,

Un o di mimo nihin.

2

Okan yi y’o je ile Re;

crMo gbohun Emi Re

Wipe, loto, mo mbo kankan

On ki se eleke.

3

mfAde ogo ti ododo

Ti mo nwo niwaju,

’Gba m’ba segun lagbara Re

Un o gbamu, un o si de.

4

fMo f’ayo wo ile ’leri

Lati oke Pisga,

Ireti mi ki o saki

Ireti t’o logo!

5

crO mbe ago amo yi wo,

O ngbon ’le ti y’o gbe;

mfKrist’ ba je wa l’oj’ayo yi,

Si nu tempili Re!

6

Mo mo pe O wa pelu mi,

crSugbpn eyi ko to,

A fi b’O fi paradise

Mule li okan mi.

7

mpOlorun mi, f’ara Re han,

Kun gbogbo afo yi;

IWO l’o le kun okan mi,

Ma bo, Olorun mi!