Hymn 653
E fi okan nyin bale; nitori ipadawa Oluwa ku si dede.
Meter: 6.4.6.7.7.
Scripture: Jak. 5:8
1
mfJesu le de loni
Ojo ayo!
fUn o si ri Ore mi,
Gbogbo wahala y’o tan
Bi Jesu ba de loni.
CHORUS
fOjo ayo! Ojo nla Ologo.
mpUn o fi suru duro d’ojo na
Laipe un o ri Oluwa mi
fOjo ayo! Ojo nla Ologo.
2
mfBoya un o lo loni
Ojo ayo!
fDabi eni ngb’ohun
Orin awon ayanfe
Bi pe loni ni uno lo.
3
mfEmi o se kanju
Ojo ayo?
fEru ’ji ko ba mi
’Mole tan l’ebute na
Nitori O wa n’tosi.
4
mfUn o maje oloto,
Ojo ayo!
fUn o si makede Re,
Bi mo ti feran Re to,
On l’ohun gbogbo fun mi.