Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 658

Afunrugbin kan jade lo lati funrugbin.

Meter: 7.6.7.6. Triple

Scripture: Mat. 13:3

1

crA gbe lo fun ’rugbin re;

’Rugbin si farasin

Ojo pupo l’o koja

Ki o to ru jade;

mfOorun ti nran mu gbona,

Ojo si mu dagba,

Oko pon fun ikore

Loju wa leekan si,

fYin Afunrugbin torun

T’o fi eso fun wa,

T’o bomirin lakoko

T’o si mu pon fun wa.

2

fWo! Afunrugbin t’orun

Nlo funrugbin iye

O nf’owo at’ ese Re

Fon oro igbala,

Laarin Ijo Re nihin,

Okan wa l'oko Re;

mpE jek’ a s’eso pupo

Fun ere laalaa Re

’Kore na y’oti dun to

T’o kun f’opo ire,

Eyi l’ope otito,

Akoso aye wa.

3

mfJesu nfunrugbin miran

Sinu ile mimo,

’Gbati ile gba oku

Awon ti On ku fun;

fB’ako tile leri won

A mo pe won y’o ji;

O daju pe won wa ni

ffParadise ayo,

Ile ikore t’o kun

F’awon eni-mimo

Ti won wo ewu Kristi,

Ti won d’ade wura!

4

crAfunrugbin ti orun

Y’o kore n’ijo kan,

fY’o si f’ayo pada wa

Pelu awon Tire;

’Gbana y’ose idajo

Y’o si fe iyangbo

Sinu ileru ina

Ti ki o ku titi;

mpIwo Olukore nla,

Saanu wa l’ojo na

T’Iwo y’o se ikore,

Ma si se ta wa nu.