Hymn 66
E fi iyin fun Oluwa.
Meter: 12.10.12.10. D
Scripture: OD. 106:1
fFi iyin fun Jesu, Olurapada wa,
Ki aye k’okiki ife Re nla,
Fi iyin fun! Eyin Angeli o’logo,
F’ola at’ogo fun oruko Re
MfB’Olus’agutan, Jesu y’o to Omo Re,
L’apa Re l’o ngbe won le l’ojojo;
Eyin eniyan mimo ti ngb’oke Sion;
fFi iyin fun pelu orin ayo
Fi iyin fun, Jesu Olurapda wa,
MpFun wa, O t’eje Re sile, O ku,
CrOn ni apata, ati reti’gbala wa,
FYin Jesu ti a kan m’agbalebu;
MfOlugbala t’O f’ara da irora nla,
DiTi a fi ade egun de l’ori,
PEniti a pa nitori awa eda
MfOba ogo njoba titi laelae
fFi iyin fun, Jesu Olurapada wa
Ki ariwo iyin gba orun kan,
Jesu Oluwa njoba lae ati laelae,
Se l’Oba gbogb’ eyin alagbara;
A segun iku: fi ayo royin na ka,
MpIsegun re ha da, isa oku?
CrJesu ye ko tun si wahala fun wa mo
FT’ori O l’agbara lati gbala