Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 664

Emi mi si yo si Olorun Olugbala mi.

Meter: 11.8.11.8.

Scripture: Lk. 1:47

1

mpIwo niwaju eni t’okan mi nyo

Ti mo npe nigba iponju,

‘Tunu mi l’osan at’ orin mi l’oru

’Reti mi at’ igbala mi.

2

mpNibo l’o nko awon agutan Re lo,

Lati f'onje ife bo won,

Ese ti Un o fi sokun li ainidi

Tabi nikan rin l’aginju?

3

mpO siju wo, opo angeli si yo,

Pupo si duro d’oro Re;

O soro, ayeraye si gb’ohun Re,

E korin iyin s'Oluwa.

4

mfOlugbala emi y’o je Ipe Re,

Emi mo adun ohun Re;

Pa mi mo ’tori Iwo ni gbogbo mi,

Un o ma yo ninu Re titi.