Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 668

Mu okan iranse Re yo nitori Iwo Oluwa ni mo gbe okan mi s 'oke si.

Meter: 7.6.7.6.

Scripture: OD. 86:4

1

fOkan ayo mi nko ‘rin

Ife Baba orun;

O ran opo ibukun,

B’orun opo ibukun.

CHORUS

fSugbon Jesu l’O san julo (Jesu l’o san ju)

Be ni Jesu l’O san julo (Jesu l’o san ju)

N’nu gbogbo ti o yi ka (Ninu gbogbo ayo ti o yika to yika)

Jesu nikan l’O julo.

2

mpB’ayo miran gbogbo pin,

Ti ‘banuje si de,

mfJesu yio pelu mi,

Onsi dara julo.

3

mfUn o so fun elomiran

Itan or’ofe Re;

Un o ma yo n’nu isin Re

Titi un o r’oju Re.

4

f‘Gba mo ba si ri ogo

Ninu odi Jasper;

Un o ko ‘rin irapada,

P’Olugbala san ju.