Hymn 670
Nje nitorina, ara, ajigbese li awa.
Meter: 7.7.7.D.
Scripture: Rom. 8:12
1
mf’G bat’ aye yi ba koja,
Ti orun re ba si wo
Ti aba wo ’nu ogo.
T’aboju wo ehin wa,
fGbana, Oluwa, un o mo
diBi ’gbese mi ti po to.
2
f’Gba mo ba de’b’ite Re
L’ewa ti ki se t’emi,
’Gba mo ri O b’O ti ri,
Ti mo fe O l’a fe tan;
’Gbana Oluwa un o mo
diBi ’gbese mi ti po to.
3
f’Gba mba gbo orin orun,
T’o ndun bi ohun ara,
Bi iro omi pupo;
pT’o si ndun b’ohunduru,
mf’Gbana Oluwa, un o mo
diBi’gbese mi ti po to.
4
mpOluwa jo, je k’a ri
Ojiji Re l’aye yi,
pK’a mo adun ’dariji
Pelu iranwo Emi.
crKi ntile mo l’aye yi
Die ninu ’gbese mi.
5
mfOre-ofe l’o yan mi,
L’o yo mi ninu ewu,
pJesu l’Olugbala mi,
Emi so mi di mimo;
crK'O mi ki nfi han l’aye,
Bi’gbese mi ti PO to.