Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 672

E duro ninu ife mi.

Meter: 8.8.8.D.

Scripture: Jn. 15:9

1

mfJesu Oluwa, Oba mi

Gb’ohun mi nigbati mo npe

Gb’ohun mi lati ’bugbe Re

RO ’jo ore-ofe sile

crOluwa mi, mo feran Re

Je ki nle ma feran Re si.

2

pJesu mo ti jafara ju

crUn o se le fe O, b’o ti ye

Em’ o se le gb’ ogo Re ga;

Ati ewa oruko Re

Oluwa mi, mo feran Re

fJe ki nle ma feran Re si.

3

mfJesu ki l’o ri ninu mi

Ti ’fe na fi po to bayi?

crOre Re si mi ti po to!

O ta gbogbo ero mi yo

fOluwa mi, mo feran Re

Je ki nle ma feran Re si.

4

fJesu ’Wo o je orin mi,

Tire laya at'okan mi

Tire ni gbogbo ini mi

Olugbala, ’Wo ni temi,

ffOluwa mi, mo feran Re

Je ki nle ma feran Re si.