Hymn 682
Oju mi yio ma ba o lo, emi o si fun o ni isimi.
Meter: 8.7.8.7.8.7.
Scripture: Eks. 33:14
1
mpM a to wa Baba wa orun
Larin ’danwo aye yi,
Fa wa mo k’o si ma bo wa,
A ko n’iranwo miran,
mfSugbon gbogbo ’bukun l’ani
B'Olorun je Baba wa.
2
mpOlugbala, dariji wa,
IWO sa m’ailera wa,
cr’WO ti rin aye saju wa,
’WO mo egbe inu re,
Bi alare, Eni- ’kanu
N’IWO l’aginju yi ja.
3
fEmi Olorun, sokale,
F’ayo orun k’okan wa,
K’ife dapo mo iya wa
At’adun ti ki su ni,
B’a ba pese fun wa bayi,
Ki lo le da wa lamu?