Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 683

Lati fi oso fun won nipo eru, ororo ayo nipo ofo, aso iyin nipo emi ibanuje.

Meter: 9.7.9.7.9.8.9.7. & Ref

Scripture: Isa. 61:3

1

mfMo nkorin ife Olorun mi

Ti Emi Re ngbe’nu mi,

Eni t’O SO ekun mi dayo,

T’o dari ese mi ji,

mpBi ikuku tile su dede

mfY’o wa pelu mi ninu re,

O ntan imole s’okukun mi

O si nm’eru mi fuye.

CHORUS

O nso ibanuje mi d’ayo

O nfun mi n’ife ti ki sa,

fO ntan imole s’okunkun mi

O si nm’eru mi fuye.

2

mfMo nkorin ife Olugbala

Eni t’o jiya fun mi

Nibi ikoko niwaju Re

O ja gbogbo ide mi,

O mu onirobinuje yo

O nfun alare ni ‘simi,

O si nso omije di erin,

O nmu eru mi fuye.

3

mfMo nkorin ayo t’ihinrere

Fun onirobinuje,

Ihinrere ayo at’erin

Nibikibi ti mba lo,

Ti mbo aso ofo l’ara wa

Ti nmu wa ko orin iyin,

fO tan imole s’okunkun mi

O si nm’eru mi fuye.