Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 688

Ko si enikan ti o ni ife ti o tobiju eyi lo, pe enikan fi emi re lele nitori awon ore re.

Meter: 8.7.8.7.D.

Scripture: Jn. 15:13

1

mfM o l’Ore kan, ife Re PO!

O fe mi k’emi t’o m’O;

crOkun ife l’O fi fa mi,

O si demi mo ’ra Re;

Koko ’fe Re t’a ko le tu,

Lo mo okan mi sibe;

fMo je Tire, On je temi,

Lae ati titi laelae.

2

mfMo l’Ore kan, ife Re po

O ku lati gba mi la;

crIye nikan ko l’O fun mi

O fi ara Re ji mi,

Nko ni p’ohun kan ni temi

Un o pamo f’Olufunmi;

fOkan, agbara, emi mi

Tire, ni titi laelae.

3

mfMo l’Ore kan, ife Re po

Gbogb’ agbara l’a fi fun

K’ O le so mi li ajo mi,

K’ O si mu mi de orun

fOgo ailopin ntan ‘mole,

Lati fun mi li okun;

Un o sora, un o sise un o ja,

Lehin na, un o simi lae.

4

mfMo l’Ore kan, ife Re po,

Oniyonu, Oloto!

Olugbimo at’Amona,

Alabo t’o lagbara!

crKini ‘ba le ya mi lodo

Eni fe mi po to yi;

Iye, iku? Aye, egbe?

fBeko! Mo je Tire lae.