Hymn 69
Oruko Oluwa ni ki ayin.
Meter: L.M & Ref
Scripture: OD. 113:3
1
fB’oruko Jesu ti dun to,
Ogo ni fun Oruko Re
O tan banuje at’ogbe
Ogo ni fun Oruko Re
CHORUS
Ogo f’oko Re, Ogo f’oko Re,
Ogo f’oruko Oluwa
Ogo f’oko Re, Ogo f’oko Re,
Ogo f’oruko Oluwa
2
O wo okan to gb’ogbe san
Ogo ni fun Oruko Re
Onje ni f’okan t’ebi npa,
Ogo ni fun Oruko Re
3
O tan aniyan elese,
Ogo ni fun oruko Re
O fun alare ni simi
Ogo ni fun oruko Re
4
Nje un o royin na f’elese,
Ogo ni fun Oruko Re
Pe mo ti ri Olugbala
Ogo ni fun Oruko Re.