Hymn 691
Anu se e.
Meter: 7.6.7.6.8.8. & Ref.
Scripture: Lk. 10:33
1
mfIfe l’o fi wa emi
Ti eru ese npa,
O gbe mi s’ejika Re
Pada bowa s’agbo
fAngeli nfi ayo korin
Pelu awon ogun orun.
CHORUS
ffA! Ife t’o wa mi,
A! Eje t’o ra mi,
Suru pelu ore-ofe Re
T’o fa mi pada bo wa s’agbo!
2
mpMo gbogbe, mo fere ku
O tu ororo si;
O so fun mi jeje pe:
pp"Temi ni iwo se!”
fNko gb’ohun t’o dun to ’yi ri
O mu okan are mi yo.
3
O f’apa iso han mi,
N’tori mi l’O jiya;
A de li ade egun
Lati fi se esin;
Nko m’ohun t’O ri l’ara mi
T’o fi jiya po be fun mi.
4
mpMo joko niwaju Re,
N’nu ’mole oju Re;
Mo si nfi iyanu nla
Ranti ibukun Re;
fAyeraye fere ma to
Lati fi korin iyin Re.
5
B’akoko ti nkpja lo
N’isimi pipe de;
fMo nreti owuro ni
Ti o dara julo,
’Gba’ On y’o pe wa sodo Re
B’iyawo Re, lailaba won.