Hymn 693
Nkan wonyi ni mo palase fun nyin pe ki enyin ki o fe omonikeji nyin.
Meter: S.M.
Scripture: Jn. 15:17
1
mf‘Fe enikejire,”
Ase Oluwa ni;
O sa fara Re sapere,
Ni fife t’O fe wa.
2
mf“Fe enikeji re”
N’ire tabi n’ija;
O ko wa pe k’a f’ota wa,
K’a fore san ibi.
3
mf“Fe enikejire,”
crOluwa nke tantan;
fO ye ki gbogbo wa mura,
K’a f enikeji wa.
4
mf“Fe enikejire,”
At’ aladugbo re,
Pelu gbogb’ eni yi o ka,
At’ota re pelu.
5
K’a f enikeji wa,
Bi Jesu ti fe wa
Jesu sa fe awon ota Re,
O si sure fun won.