Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 695

Ife tire ni ki a se, bi ti orun, beni li aiye.

Meter: C.M.

Scripture: Mat. 6:10

1

fJesu, lye, Oto, Ona,

Eni ti mo gbagbo,

B’O ti ko mi, mo ngbadura,

Mo nreti ki nri-gba.

2

mfJeki nma se ’fe Re laye,

Bi won ti nse l’orun,

Awon ti nri O lori ’te

Ti nsogo n’nu 'fe Re.

3

Mo ntoro ore ofe Re.

Lati le se 'fe Re.

B’awon angel’ ti nr’oju Re.

Ti nmu oro Re se.

4

diDajudaju, em’ elese

Y’o sin O laifoya;

mfOkan mi ko lati tun gba

Adura etan mi.

5

’Gbat’ O ba s’ise gbogbo tan,

Emi y’o mo n’inu,

crNki o dese l’ohunkohun;

N’tori angel’ ki se.

6

fEmi ki o tun ya O mo,

Nki o si da O mo,

Emi y’o fe O laisetan;

N’tori angel’ ni fe.

7

Un o ma se ife mimo Re

Em’ otos’ elese,

’Gba m’ba fe O tokan-tokan,

Un o ma p’ofin Re mo.

8

Or’ofe nipa atunse

Li a o fifun mi,

Un o si ma se’fe Re

B’angel’ ti n se.