Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 698

Nigbati nwon ko si ni ti nwon o san, Tinu-tinu li o dariji awon mejeji.

Meter: S.M.

Scripture: Lk. 7:42

1

mfO fun mi l’edidi,

Gbese nla ti mo je

B’o ti fun mi, O si rerin

pPe; Mase gbagbe Mi.

2

mfO fun mi l’edidi

O san igbese na

B’o ti fun mi O si rerin

Wipe; ma ranti Mi!

3

mfUn o p’edidi na mo

B’igbese tile tan;

O nso ife Eni t’o san

Igbese na fun mi.

4

fMo wo mo si rerin

pMo tun wo mo sokun

mfEri ife Re si mi ni

Un o toju re titi.

5

Ki tun s’edidi mo,

Sugbon iranti ni!

fPe gbogbo igbese mi ni

Imanueli san.