Hymn 699
Eniti ojoko ni ibi ikoko Oga-ogo ni yio ma gbe a be ojiji Olodumare.
Meter: 8.7.8.7.D.
Scripture: OD. 91:1
1
mfN’nu ojiji Oga-ogo
crL’abo mi y’o wa titi;
N’tori oju Re ti ki sun
fNso mi n’gba gbogbo sibe
fEmi ngbe ninu ojiji
ti Oba awon oba;
O f’iye-apa Re bo mi,
Nibe ni mo si simi.
2
mfN’nu ojiji Oga-ogo
fMo bo loW’ eru gbogbo
N’tori apa Re gba mi mu,
O si yi mi kakiri.
3
mfN ’nu ojiji Oga-ogo
fIbi kan kole de ‘be;
Krist’ n’ireti, asa, abo,
Olugbala, gbogbo mi.