Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 7

Li ale, li owuro, ati li osan li emi o ma gbadura

Meter: S.M.

Scripture: OD 55:17

1

mfWa s’adura ooro,

Kunle k’a gbadura,

fAdura ni opa Kristian,

Lati b’Olorun rin

2

mfL’osan, wole labe

Apat’ayeraye,

pItura ojiji Re dun

Nigba t’orun ba mu

3

mfJe ki gbogbo ile

Wa gb’adura l’ale;

Ki ile wa di t’Olorun

diAti ‘bode orun

4

pNigbat’od’oganjo,

Je k’a wi l’emi pe,

fMo sun, sugbon okan mi ji,

Lati ba O s’ona