Hymn 70
E yin oruko Oluwa Olorun yin, eniti o fi iyanu ba yin lo.
Meter: 6.6.8.4. D
Scripture: Joe 2:26
fYin Olorun Abra’am,
Ti O njoba l’oke
Eni t’O ti wa titi lae
Olorun ‘fe
“Jehofa nla Emi”
Gbogbo eda jewo,
Mo fi ‘bukun Re
Titi laelae
mfYin Olorun Abra’am,
Nip’ase Eni ti
Mmo dide, mo si wa ‘tunu
Lowo ‘tun Re;
Mo ko aye sile;
Ogbon at’ola re;
On nikan si ni ipin m
At’asa mi
fOn na ti se ‘leri;
Mo gbekele eyi,
U n I fi iye idi goke
Lo si orun
Un o ma wo oju Re
Un o si yin ipa Re,
Un o korin ‘yanu to’or’ofe
Titi laelae
diB’agbara eda pin,
T’aye at’esu nde,
Un o d’ojuko ona kenan’
Nipa ‘se Re
Un o re odo koja
Bi Jesu wa lokan
Un o koja n’nu igbo didi
Lo s’ona mi.
mfOba Oke orun
Olor’Angeli nke
PWipe “Mimo, Mimo, Mimo”
Oba titi
CrEn ‘ti ki yi pada,
FTi y’o si wa laelae
FfJehofa Baba, “Emi ni”
Awa yin O
fGbogbo ‘gbe asegun
Yin Olorun loke,
Baba, Omo at,Emi, ni
Won nke titi
FfYin Olorun Abra’am!
Un o ba won korin na,
Tire l’agbara at’ola
Pelu iyin.