Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 701

Ngo fe O Oluwa agbara mi.

Meter: 8.8.8.D

Scripture: OD. 18:1

1

fUn o feran Re, ’Wo odi mi,

Un o feran Re, ’Wo ayo mi

Un o feran Repatapata,

Iwo nikan, pelu ’se Re

crUn o feran Re, tit’ okan mi,

Y’o fi kun fun ife rere.

2

mfIwo orun ti a ko da,

Mo s’ope fun imole Re

Mo s’ope t’O segun ota

T’O wo ogbe okan mi san

Mo s’ope n’tori ohun Re

Nmu okan mi yo ninu Re

3

mfGbe mi ro n’nu ’re ije yi

Ma je k’emi tun sako lo;

crFun ese mi l’okun, lati

Ma te siwaju l’ona Re,

ff’Wo Oluwa, Alagbara

F’imole Re te mi lorun.

4

fUn o feran Re, ’WO ade mi

Un o feran Re, Oluwa mi;

diUn o feran Re nigba gbogbo,

L’ojo ibi, l’ojo ire,

p’Gbati ojo iku, ba de,

fUn o feran Re titi laelae.